Ifi 19:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun mi pe, Kọwe rẹ̀, Ibukún ni fun awọn ti a pè si àse-alẹ igbeyawo Ọdọ-Agutan. O si wi fun mi pe, Wọnyi ni ọ̀rọ otitọ Ọlọrun.

Ifi 19

Ifi 19:1-11