Ifi 19:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ jẹ ki a yọ̀, ki inu wa ki o si dùn gidigidi, ki a si fi ogo fun u: nitoripe igbeyawo Ọdọ-Agutan de, aya rẹ̀ si ti mura tan.

Ifi 19

Ifi 19:1-9