Ifi 19:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn àgba mẹrinlelogun nì, ati awọn ẹda alãye mẹrin nì si wolẹ, nwọn si foribalẹ fun Ọlọrun ti o joko lori itẹ́, wipe, Amin; Halleluiah.

Ifi 19

Ifi 19:1-7