Ifi 18:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni ijọ kan ni iyọnu rẹ̀ yio de, ikú, ati ibinujẹ, ati ìyan; a o si fi iná sun u patapata: nitoripe alagbara ni Oluwa Ọlọrun ti nṣe idajọ rẹ̀.

Ifi 18

Ifi 18:6-18