Ifi 17:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Angẹli si wi fun mi pe, Nitori kili ẹnu ṣe yà ọ? emi o sọ ti ijinlẹ obinrin na fun ọ, ati ti ẹranko ti o gùn, ti o ni ori meje ati iwo mẹwa.

Ifi 17

Ifi 17:2-12