Ifi 16:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si gbọ́ angẹli ti omi nì wipe, Olododo ni Iwọ Ẹni-Mimọ́, ẹniti o mbẹ, ti o si ti wà, nitoriti iwọ ṣe idajọ bayi.

Ifi 16

Ifi 16:1-6