Ifi 13:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ti ngbe ori ilẹ aiye yio si mã sin i, olukuluku ẹniti a kò kọ orukọ rẹ̀ sinu iwe iyè Ọdọ-Agutan ti a ti pa lati ipilẹṣẹ aiye.

Ifi 13

Ifi 13:4-14