Ifi 12:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si bí ọmọkunrin kan ti yio fi ọpá irin ṣe akoso gbogbo awọn orilẹ-ède: a si gbà ọmọ rẹ̀ lọ soke si ọdọ Ọlọrun, ati si ori itẹ́ rẹ̀.

Ifi 12

Ifi 12:1-10