Ifi 12:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dragoni na si binu gidigidi si obinrin na, o si lọ ba awọn iru-ọmọ rẹ̀ iyokù jagun, ti nwọn npa ofin Ọlọrun mọ́, ti nwọn si di ẹrí Jesu mu.

Ifi 12

Ifi 12:14-17