Ifi 11:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ninu awọn enia, ati ẹya, ati ède, ati orilẹ, nwọn wo okú wọn fun ijọ mẹta on àbọ, nwọn kò si jẹ ki a gbé okú wọn sinu isà okú.

Ifi 11

Ifi 11:1-11