Ifi 11:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si gbọ́ ohùn nla kan lati ọrun wá nwi fun wọn pe, Ẹ gòke wá ìhin. Nwọn si gòke lọ si ọrun ninu awọsanma; awọn ọtá wọn si ri wọn.

Ifi 11

Ifi 11:11-19