Iṣe Apo 9:42-43 Yorùbá Bibeli (YCE) O si di mimọ̀ yi gbogbo Joppa ká; ọpọlọpọ si gba Oluwa gbọ́. O si ṣe, o gbé ọjọ pipọ ni Joppa