Iṣe Apo 9:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, bi Peteru ti nkọja nlà ẹkùn gbogbo lọ, o sọkalẹ tọ̀ awọn enia mimọ́ ti ngbe Lidda pẹlu.

Iṣe Apo 9

Iṣe Apo 9:30-37