Iṣe Apo 9:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si nfi igboiya sọ̀rọ li orukọ Jesu Oluwa, o nsọrọ lòdi si awọn ara Hellene, o si njà wọn niyàn: ṣugbọn nwọn npete ati pa a.

Iṣe Apo 9

Iṣe Apo 9:20-30