Iṣe Apo 9:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnu si yà gbogbo awọn ti o ngbọ́, nwọn si wipe, Ẹniti o ti fõro awọn ti npè orukọ yi ni Jerusalemu kọ li eyi, ti o si ti itori na wá si ihinyi, lati mu wọn ni didè lọ sọdọ awọn olori alufa?

Iṣe Apo 9

Iṣe Apo 9:14-27