Iṣe Apo 9:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si jẹun, ara rẹ̀ mokun: Saulu si wà pẹlu awọn ọmọ-ẹhin ni Damasku ni ijọ melokan.

Iṣe Apo 9

Iṣe Apo 9:12-22