Iṣe Apo 8:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ibi iwe-mimọ́ ti o si nkà na li eyi, A fà a bi agutan lọ fun pipa; ati bi ọdọ-agutan iti iyadi niwaju olurẹrun rẹ̀, bẹ̃ni kò yà ẹnu rẹ̀:

Iṣe Apo 8

Iṣe Apo 8:29-34