Iṣe Apo 8:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Simoni dahùn, o si wipe, Ẹ gbadura sọdọ Oluwa fun mi, ki ọ̀kan ninu ohun ti ẹnyin ti sọ ki o máṣe ba mi.

Iṣe Apo 8

Iṣe Apo 8:22-26