Iṣe Apo 8:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Simoni tikararẹ̀ si gbagbọ́ pẹlu: nigbati a si baptisi rẹ̀, o si mba Filippi joko, o nwò iṣẹ àmi ati iṣẹ agbara ti nti ọwọ́ Filippi ṣe, ẹnu si yà a.

Iṣe Apo 8

Iṣe Apo 8:4-22