Iṣe Apo 7:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn baba nla si ṣe ilara Josefu, nwọn si tà a si Egipti: ṣugbọn Ọlọrun wà pẹlu rẹ̀.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:1-15