Iṣe Apo 7:60 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kunlẹ, o kigbe li ohùn rara pe, Oluwa, má kà ẹ̀ṣẹ yi si wọn li ọrùn. Nigbati o si wi eyi, o sùn.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:50-60