Iṣe Apo 7:52 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tani ninu awọn woli ti awọn baba nyin kò ṣe inunibini si? nwọn si ti pa awọn ti o ti nsọ asọtẹlẹ ti wíwa Ẹni Olõtọ nì; ẹniti ẹnyin si ti di olufihàn ati olupa:

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:49-58