Iṣe Apo 7:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si pada, o fi wọn silẹ lati mã sìn ogun ọrun; bi a ti kọ ọ ninu iwe awọn woli pe, Ẹnyin ara ile Israeli, ẹnyin ha mu ẹran ti a pa ati ẹbọ fun mi wá bi li ogoji ọdun ni iju?

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:37-46