Iṣe Apo 7:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

On li o mu wọn jade, lẹhin igbati o ṣe iṣẹ iyanu ati iṣẹ àmi ni ilẹ Egipti, ati li Okun pupa, ati li aginjù li ogoji ọdún.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:33-43