Iṣe Apo 7:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wipe, Emi li Ọlọrun awọn baba rẹ, Ọlọrun Abrahamu, ati Ọlọrun Isaaki, ati Ọlọrun Jakọbu. Mose si warìri, kò si daṣa lati wò o mọ́.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:31-33