Iṣe Apo 7:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ogoji ọdún si pé, angẹli Oluwa farahàn a ni ijù, li òke Sinai, ninu ọwọ́ iná ni igbẹ́.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:24-40