Iṣe Apo 7:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li akokò na li a bí Mose, ẹniti o li ẹwà pipọ, ti nwọn si bọ́ li oṣù mẹta ni ile baba rẹ̀:

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:17-21