Iṣe Apo 7:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nigba keji Josefu fi ara rẹ̀ hàn fun awọn arakunrin rẹ̀; a si fi awọn ará Josefu hàn fun Farao.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:11-16