Iṣe Apo 7:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iyan kan si wá imu ni gbogbo ilẹ Egipti ati ni Kenaani, ati ipọnju pipọ: awọn baba wa kò si ri onjẹ.

Iṣe Apo 7

Iṣe Apo 7:1-15