Iṣe Apo 6:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọ̀rọ Ọlọrun si gbilẹ; iye awọn ọmọ-ẹhin si pọ̀ si i gidigidi ni Jerusalemu; ọ̀pọ ninu ẹgbẹ awọn alufa si fetisi ti igbagbọ́ na.

Iṣe Apo 6

Iṣe Apo 6:5-15