Iṣe Apo 5:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Peteru si wi fun u pe, Ẽṣe ti ẹnyin fohùn ṣọkan lati dán Ẹmí Oluwa wò? wò o, ẹsẹ awọn ti o sinkú ọkọ rẹ mbẹ li ẹnu ọ̀na, nwọn o si gbé ọ jade.

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:6-16