Iṣe Apo 5:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li ojojumọ́ ni tẹmpili ati ni ile, nwọn kò dẹkun ikọ́ni, ati lati wasu Jesu Kristi.

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:39-42