Iṣe Apo 5:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o wà nibẹ, tirẹ ki iṣe? nigbati a si ta a tan, kò ha wà ni ikawọ ara rẹ? Ẽha ti ṣe ti iwọ fi rò kini yi li ọkàn rẹ? enia ki iwọ ṣeke si bikoṣe si Ọlọrun.

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:1-13