Iṣe Apo 5:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ọkan ninu ajọ igbimọ, ti a npè ni Gamalieli, Farisi ati amofin, ti o ni iyìn gidigidi lọdọ gbogbo enia, o dide duro, o ni ki a mu awọn aposteli bì sẹhin diẹ;

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:28-38