Iṣe Apo 5:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awa bá ile tubu o sé pinpin, ati awọn oluṣọ duro lode niwaju ilẹkun: ṣugbọn nigbati awa ṣílẹkun, awa kò bá ẹnikan ninu tubu.

Iṣe Apo 5

Iṣe Apo 5:18-31