Iṣe Apo 4:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si kìlọ fun wọn si i, nwọn jọwọ wọn lọwọ lọ, nigbati nwọn kò ti ri nkan ti nwọn iba fi jẹ wọn ni ìya, nitori awọn enia: nitori gbogbo wọn ni nyìn Ọlọrun logo fun ohun ti a ṣe.

Iṣe Apo 4

Iṣe Apo 4:19-29