Iṣe Apo 4:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Peteru on Johanu dahùn, nwọn si wi fun wọn pe, Bi o ba tọ́ li oju Ọlọrun lati gbọ́ ti nyin jù ti Ọlọrun lọ, ẹ gbà a rò,

Iṣe Apo 4

Iṣe Apo 4:15-22