Iṣe Apo 4:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si kiyesi igboiya Peteru on Johanu, ti nwọn si mọ̀ pe, alaikẹkọ ati òpe enia ni nwọn, ẹnu yà wọn; nwọn si woye wọn pe, nwọn a ti ma ba Jesu gbé.

Iṣe Apo 4

Iṣe Apo 4:10-19