Iṣe Apo 3:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti ọrun kò le ṣaima gbà titi di igba imupadà ohun gbogbo, ti Ọlọrun ti sọ lati ẹnu awọn woli rẹ̀ mimọ́ ti nwọn ti mbẹ nigbati aiye ti ṣẹ̀.

Iṣe Apo 3

Iṣe Apo 3:20-26