Iṣe Apo 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ohun ti Ọlọrun ti sọ tẹlẹ lati ẹnu gbogbo awọn woli wá pe, Kristi rẹ̀ yio jìya, on li o muṣẹ bẹ̃.

Iṣe Apo 3

Iṣe Apo 3:9-24