Iṣe Apo 3:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si mọ̀ pe on li o ti joko nṣagbe li ẹnu-ọ̀nà Daradara ti tẹmpili: hà si ṣe wọn, ẹnu si yà wọn gidigidi si ohun ti o ṣe lara rẹ̀.

Iṣe Apo 3

Iṣe Apo 3:8-14