Iṣe Apo 28:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

O nwasu ijọba Ọlọrun, o si nfi igboiya gbogbo kọ́ni li ohun wọnni ti iṣe ti Jesu Kristi Oluwa, ẹnikan kò da a lẹkun.

Iṣe Apo 28

Iṣe Apo 28:22-31