Iṣe Apo 28:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awa nfẹ gbọ́ li ẹnu rẹ ohun ti iwọ rò: nitori bi o ṣe ti ìsin iyapa yi ni, awa mọ̀ pe, nibigbogbo li a nsọ̀rọ lòdi si i.

Iṣe Apo 28

Iṣe Apo 28:18-30