Iṣe Apo 28:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati awọn Ju sọ̀rọ lòdi si i, eyi sún mi lati fi ọ̀ran mi lọ Kesari; kì iṣe pe mo ni nkan lati fi orilẹ-ède mi sùn si.

Iṣe Apo 28

Iṣe Apo 28:14-28