Iṣe Apo 27:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awa nlọ jẹ́jẹ li ọjọ pipọ, ti awa fi agbara kaka de ọkankan Knidu, ti afẹfẹ kò bùn wa làye, awa lọ lẹba Krete, li ọkankan Salmone;

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:3-9