Iṣe Apo 27:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn balogun ọrún nfẹ gbà Paulu là, o kọ̀ ero wọn; o si paṣẹ fun awọn ti o le wẹ̀ ki nwọn ki o kọ́ bọ si okun lọ si ilẹ,

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:34-44