Iṣe Apo 27:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati awọn atukọ̀ nwá ọ̀na ati sá kuro ninu ọkọ̀, ti nwọn si ti sọ igbaja kalẹ si oju okun bi ẹnipe nwọn nfẹ sọ idakọró silẹ niwaju ọkọ̀,

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:29-33