Iṣe Apo 27:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si wọ̀n okun, nwọn ri i o jìn li ogún àgbaká: nigbati nwọn si sún siwaju diẹ, nwọn si tún wọ̀n okun, nwọn ri i o jìn ni àgbaká mẹ̃dogun.

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:23-34