Iṣe Apo 27:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn wà ni aijẹun li ọjọ pipọ, nigbana Paulu dide larin wọn, o ni, Alàgba, ẹnyin iba ti gbọ́ ti emi, ki a máṣe ṣikọ̀ kuro ni Krete, ewu ati òfo yi kì ba ti ba wa.

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:13-27