Iṣe Apo 27:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si gbé e soke, nwọn nṣe iranlọwọ, nwọn ndì ọkọ ni isalẹ; nigbati nwọn si bẹ̀ru ki a ma ba gbá wọn sori iyanrìn diẹ̀, nwọn tagbokun, nwọn si ngbá kiri.

Iṣe Apo 27

Iṣe Apo 27:7-20